Strategy Àjọṣepọ̀ Wikimedia/Àwọn Àpèjọ/Ìjíròrò Kárí-ayé ti Ìwé-àdéhùn Àjọṣepọ̀, 26-27 Oṣù Kẹ́fà 2021
Ìwé-Àdéhùn Àjọṣepọ̀ yí ò fi ipa àti ojúṣè oníkálukú àti oníṣẹ́ hàn lórí àjọṣepọ̀ Wikimedia, yí ó sì ṣ'ètò Ìgbìmọ̀ ìṣàkóso àgbáyé fún ìdarí àjọṣepọ̀ yìí. Ìwé-Àdéhùn yìí jẹ́ òkúta igun-ilé ìsodàṣa Strategy Àjọṣepọ̀. Nítorípé a nílò láti bẹ̀ẹ̀rẹ̀ sí ní ṣiṣẹ́ lórí ìwé-àṣẹ pàtàkì yìí, à nya ipele ìjíròrò tó'kàn sọ́tọ̀ fún Ìgbìmọ̀ kíkọ Ìwé-Àdéhùn Àjọṣepọ̀.
Why participate?
Ìwé-Àdéhùn yìí kan Àjọṣepọ̀ wa kárí-ayé. A nílò ìkópa lát'ọ̀dọ̀ gbogbo àwọn oníṣẹ́ wa kárí àgbáyé, ní pàtàkì jùlọ lát'ọ̀dọ̀ àwọn ẹgbẹ́ tí a kò fojúsí dáradára tẹ́lẹ̀. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìjíròrò ló ti wáyé lórí Ìwé-Àdéhùn yìí, a sì ní lò àwọn èrò si, láti pọhùnpọ̀ lórí ìlànà tí ó yẹ fún ìṣẹ̀dá ìgbìmọ̀ kíkọ.
Ọ̀nà tí o fi lè kópa ni:
- Join a text conversation, in English or in another language.
- Join a local meeting, also in your preferred language.
- Join the Global Conversation on June 26-27.
- Join the follow up conversation to define the committee creation plan.
Wo abala Àwọn Ìjíròrò Ìbílẹ̀ ní ìsàlẹ̀ láti darapọ̀ mọ́ ìjíròrò tó súnmọ́ ọ.
Ṣíṣ'ẹ̀dá Ìgbìmọ̀ fún kíkọ
À nretí wípé Ìgbìmọ̀ fún kíkọ Ìwé-àdéhùn Àjọṣepọ̀ yí ó ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíí ẹgbẹ́ 15 tó já fáfá fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ oṣù. Wọn yí ó gba ìrànlọ́wọ́ lá t'ọ̀dọ̀ àwọn amòye ní ìgbà-dé-ìgbà, àtúnyẹ̀wò lát'ọ̀dọ̀ àwọn ará Wikimedia, àti àyè fún ìdánilẹ́kọ̀ àti owó fún àsìkò wọn. Nígbàtí wọ́n bá ti parí kíkọ ọ̀rọ̀ ìmúlò, ìgbìmọ̀ yìí yíò darí ètò ìfọwọ́sí àwọn ará Wikimedia.
Ìbéèrè mẹ́tàa
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìjíròrò ló ti wáyé lórí Ìwé-Àdéhùn Àjọṣepọ̀, pẹ̀lú àwọn àbá lórí ìṣẹ̀dá rẹẹ̀. Àwọn ìpohùnpọ̀ ti wáyé, ìyapa èrò nọ́ọ̀ sì ti wáyé. Àwọn olùṣètò Strategy Àjọṣepọ̀ ti fi ìbéèrè mẹ́tàa hàn tó nílò ìdáhùn láti lè ṣẹ̀dá ìgbìmọ̀ nọ́ọ̀. À nṣètò àwọn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìjíròrò gẹ́gẹ́ bí ipa wá ti ká, láti gba àwọn èsì àwọn ìbéèrè yíì sílẹ̀. Pẹ̀lúpẹ̀lú, à nṣètò àwọn ìpàdé ayélujára lórí ìbéèrè kọ̀ọ̀kan ní 26-27 Oṣù Kẹfà.
Lẹ́yìn ipele yìí, a ó gba àwọn èsì sílẹ̀, a ó sì pèsè ìwe ìmọ̀ràn lórí ìṣẹ̀dá ìgbìmọ̀ kíkọ, fún ìpinnu àwọn ará àjọṣepọ̀.
1. Irú ìṣàjọ wo ni ó yẹ kí ìgbìmọ̀ nọ́ọ̀ ní, tí abá nsọ nípa ojúṣe nínú àjọṣepọ̀, ìwọ̀n akọ àti abo, agbègbè, àwọn ẹ̀ka iṣẹ́ Wikimedia, àti àwọn ìwà ìdékùn ojú-ìsájú míràn?
- There is broad agreement on the diversity and the expertise that the committee needs to have as a team (see Diversity & Expertise matrix).
- Some believe that there should be specific seats or quotas assigned to members with specific qualities (affiliation, region, gender…), some believe that the composition should be flexible as long as it meets the diversity and expertise requirements.
2. Kíni ìlànà tí ó dára jùlọ fún yíyan àwọn ará ìgbìmọ̀ yìí láti ríi dájú wípé aní ẹgbẹ́ onírúurú tí ó sì já fáfá?
- There is broad agreement on the need to form a diverse and competent team, but opinions differ about how to achieve this.
- Some believe that self-nominations, invitations and appointments are the best way to form the team, some believe that it is better to have a majority of seats elected by the communities and the affiliates.
- In the case of appointments, some believe the decisions could come from a self-appointed group with participation of the Foundation, some prefer a selection committee that would be elected.
- In the case of elections, there are different opinions about the distribution of seats elected by communities, elected by affiliates, and appointed by the Foundation.
3. Irú ìwọ̀n iṣẹ́ wo ni ó yẹ kí a retí lát'ọ̀dọ̀ àwọn ará ìgbìmọ̀, ní pàtàkì jùlọ, ìwọ̀n wákàtí ní ọ̀sẹ̀, pẹ̀lú iye oṣù iṣẹ́?
- There is broad agreement that committee membership drafting a Charter is serious work, but too demanding requirements are likely to affect the diversity and competence of the team.
- The default expectation of committees is that members stay for the entirety of the project and they carry most of the work.
- Some ideas have been suggested to reduce the burden, like rely on professionals for certain tasks, organize volunteer groups to work on certain questions, or include a process for membership renewals.
Àwọn ìjíròrò ìbílẹ̀
Ẹnikẹ́ni ni ó lè ṣètò ìjíròrò àwòrán tàbí t'ọ̀rọ̀ láti dámọ̀ràn lórí ìbéèrè mẹ́tàa yìí ní èdè tí ó bá wù wọ́n. Èróngbà wa ni láti gbàsílẹ̀ àwọn ìbéèrè, èrò, ibi ìpọhùnpọ̀ àti ìyapa ní ẹ̀ka àjọṣepọ̀ rẹ. Jọ̀wọ́ fi ìjíròrò rẹ sí ìsàlẹ̀, kí a bà le bojútó àwọn èsì.
O tún lè fún àtìlẹyìn ìṣètò fún ẹ̀ka àjọṣepọ̀ rẹẹ nípa kíkàn sí strategy2030 wikimedia.org. Pẹ̀lú àtìlẹyìn lát'ọ̀dọ̀ àwọn olùṣètò, a ó gbè àkójọpọ̀ èsì àkọ́kọ́ ìjíròrò ìbílẹ̀ kọ̀ọ̀kan jáde ní Ọjọ́ Jímọ̀ 26 Oṣù Kẹ́fà.
Ìjíròrò ojú-ewé ọ̀rọ̀
- Metawiki (comments in other languages welcome)
- Movement Strategy Global Events Telegram group (English, comments in other languages welcome)
- Italian: Conversation page on the Wikipedia in Italian, Aggiornamenti sulla strategia Wikimedia on Telegram
- Korean: Conversation page on Korean-language Wikipedia
- Spanish: Estrategia Wikimedia and Grupo de gobernanza de WM on Telegram (Report)
- conversation in english
- Indonesian: Village Pump discussion
- Malay: Village Pump discussion
- Russian: Village Pump discussion (Report)
- German: Survey: Movement Charter – 3 Questions
- Arabic: Summary Report
Àpèjọ orí ayélujára
- ESEAP #10 General Meeting (19 June 2021, 0200 UTC)
- African Meetings Report (22nd and 23rd June 2021, 7pm UTC)
- South Asia Meeting Report (25 June 2021, 1:00 pm UTC)
- Report of the Movement Charter Francophone conversation (24th June 2021)
Tún wo
- Movement Charter Drafting Group
- 2021-01-24 Report of the Interim Global Council conversations (includes discussion about the Movement Charter drafting committee)
- 2021-03-22 Proposal for expeditious 7/7/7 committee and community ratification of Movement Charter by Pharos
- 2021-04-14 Proposal: Drafting a Movement Charter by 10 volunteers and affiliates’s staff
- 2021-05-31 Summary of the Movement Charter discussion in preparation for the June events
- 2021-06-13 Summary of the Movement Charter Global Conversation on June 12-13, including a Drafting committee set-up proposal by the Wikimedia Foundation.
- 2021-06-26 Proposal for mixed community, affiliate, and WMF selection of drafting committee by Nosebagbear
- 2021-07-01 Movement Charter/Movement Charter Drafting Group/Large Committee proposal, by Yair Rand.