Fundraising 2012/Translation/Poongothai Appeal

This page is a translated version of the page Fundraising 2012/Translation/Poongothai Appeal and the translation is 42% complete.

1 Nígbà tí mo fẹ̀yìntì tán, ọmọkùnrin mi ṣàníyàn bóyá àìníṣẹ́ yíò bàmíjẹ́. Nítoríẹ̀ ó fi Wikipedia hàn mí. Ó ṣàlàyé pé ẹniyìówù le kópa, ó sì fi hàn mí báwo.

Láti ìgbà náà, mo ti ṣèdá àwọn àyọkà lórí àwọn ìmúṣe alọ́poméjì, ìṣeéṣe, àwòrán àlàyé, ìlàìsirò àti ọ̀pọ̀lọpọ̀. Mo ti ṣe àtúnṣe tó tó 7,000 lápapọ̀.

Èdè Tamil ni mò únlò:òhun ni èdè mi tí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn tó tó ẹgbẹgbẹ̀rún 85 káàkriri àgbáyé únsọ. Bákannáà mó tun ti ṣàrùsókè àwọn fáìlì ìgbóhùn bíi 6,000 sí orí Wiktionary, láti ṣàlàyé ọ̀nà tó tọ́ tí a ṣe únpe àwọn ọ̀rọ̀ èdè Tamil. Báyìí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn ni wọ́n le ṣàjọpín èdè ẹlẹ́wà yìí.

As a teacher and a mother, I was always busy. But now that I'm retired and my children are grown, my time is my own -- all 24 hours of it! And I spend every day on Wikipedia.

I'm a volunteer. No one pays me. But helping edit Wikipedia has become my life's work.

Even though I'm not in the classroom, I'm still doing what I care about most: helping a new generation of students learn, in the language I love.

Everyone has something they can share. Please make a donation of $5, $20 or $50 to help Wikipedia thrive.

Bio

Poongothai Balasubramanian lives in Coimbatore, Tamil Nadu, where she taught for many years.

She began editing Wikipedia in 2010. Since then, she's created 250 articles and recorded pronunciations for 6,000 words.

Her Wikipedia username is inspired by her favorite novel:To Kill A Mocking Bird.