Ìwé-àdéhùn Àjọṣepọ̀
Àjọ Wikimedia jẹ́ akójọpọ̀ àwọn ènìyàn àwùjọ tí wọ́n fi ìmọ̀-ọ̀fẹ́ káàkiri àgbáyé ṣe àfojúsùn wọn. Ìwé àdéhùn àjọṣepọ̀ yí ṣe àlàálẹ̀ kókó, ọ̀nà àátọ̀ àti àlàkalẹ̀ fún gbogbo àwùjọ àwọn oníṣẹ́ Wikimedia tí ó fimọ́ ipa ati ojúṣe tẹrú-tọmọ tí ó fimọ́ àwọn alẹ́nulọ́rọ̀ nibi ìpinu ṣíṣe nínú àwùjọ wa. Ìwé yí bá gbogbo ẹni tí ó bá ti ní ohun kan ṣe pẹ̀lú àjọ Wikimedia pátá pátá, yálà ẹyọ ènìyàn kan ni tàbí ẹlẹ́gbẹ́jẹgbẹ́ tí wọ́n ń ṣiṣẹ́ pàtàkì kan tàbí òmíràn fún àjọ wa.
Sísọ àti mímọ̀ nípa kókó ohun tí àjọ Wikimedia jẹ́ ni yóò jẹ́ kí àwọn ẹlẹ́gbẹ́jẹgbẹ́ nínú àjọ Wikimedia ó lè ní ìbáṣepọ̀ tó máyán-lórí níbàámu pẹ̀lú àfojúsùn àjọ Wikimedia lápapọ̀. Èyí yóò jẹ́ kí:
- A lè mọ ọ̀nà àátọ̀ fún ìdàgbà-sókè, ìgbòòrò àti mímọ ọ̀nà tí a lè gbà tan ìmọ̀-ọ̀gẹ́ kalẹ̀ gbogbo àgbáyé lọ̀jọ́ iwájú;
- Jẹ́ atọ́nà fún ìpinnu wa;
- Yóò dín àìgbọ́raẹni-yé kú yóò sì jẹ́ kí ìrẹ́pọ̀ ati ìbárẹ́ wà láàrín àwọn lààmì-laaka láwùjọ wa.
- Dáàbò bo ẹ̀tọ́ àwọn tí ó ń fún wa lówó nínú àti lóde Wikimedia.
- Yóò jẹ́ kí a lè mọ ohun tó ń lọ.
A lè ṣe àyípadà sí ìwé yìí bí a bá fẹ́ lábẹ́ Ìyípadà.
Kókó àti àlàkalẹ̀ àjọ Wikimedia
Àjọ Wikimedia ni ó dúró lé ododo, ìfimúlẹ̀ nípa ìtànkálẹ̀ ìmọ̀-ọ̀fẹ́. Gbogbo ìrìnkerindò ìpinnu nínú àwùjọ Wikimedia ni ó dá lórí kókó ati àlàkalẹ̀ àjọ náà.
Àwọn àlàkalẹ̀ wọ̀nyí ni ó dúró lórí ètò àmúṣe-múlò ọ̀fẹ́ (free licensing), Ìbáṣepọ̀ tó sàn mọ́rán tí yóò mú àlá rere ọjọ́ iwájú wa ṣẹ.
Bí àjọ Wikimedia ṣe jẹ́ irúwá ògìrì wá yìí, síbẹ̀ àjọ náà gbára lé àwọn àlàkalẹ̀ mẹ́ta kan. Àwọn náà ni:
Lílo àṣẹ ọ̀fẹ́
Àjọ Wikimedia ni ó ń lo àṣẹ àmúṣe-múlò ọ̀fẹ́ látorí àpilẹ̀kọ, fọ́nrán, irinṣẹ́, ìtànká àti ìmúgbòòrò ìmọ̀ ọ̀fẹ́ jákè-jádò àgbáyé. Àwọn nkan mìíràn tí a gbà láti ìta wọlé náà ni a ma ń fi sí abẹ́ àṣẹ àmúṣe-múlò ọ̀fẹ́. Ohun tó jẹ àjọ Wikimedia lógún ni láti tan ìmọ̀-ọ̀fẹ́ káàkiri àgbáyé pẹ́lú kíkó ìmoọ̀ tuntun àti tàtijọ́ mọ́ra fún ìgbòòrò ìmọ̀.
Ìṣàkóso ara-ẹni àti Ìbáṣepọ̀
Ìṣípò-rọpò agbára àwọn adarí ninú àjọ Wikimedia ni kò dúró sókè nìkan, ó Ṣàngó dé orí àwọn aláfikún ìmọ̀-ọ̀fẹ́ pẹ̀lú. Àjọ Wikimedia ni wọ́n gbé àṣẹ ìṣàkóso ara-ẹni lé gbogbo àwùjọ kọ̀ọ̀kan lọ́wọ́ kí wọ́n lè ṣeé bí yóò ti rọ̀ wọ́n lọ́rùn nípa lílo ìlànà subsidiarity láti lè ma kópa nínú ìtànkálẹ̀ ìmọ-ọ̀fẹ́. Ohun tí àjọ Wikimedia ń fẹ́ ni lílo làákàyè ní kíkú fún ìṣe ojúṣe tí ó lè mú ìbáṣepọ̀ tó máyán-lórí tí ó lè yanjû ìṣòro Ọlọ́kan-ò-jọkan tí yóò si fi pàtàkì ìwé yí hàn.
Ìròyìn tí òdodo rẹ̀ ṣe é tọpa
Àfojúsùn àjọ Wikimedia ni wípé gbogbo ohun tí wọ́n bá kọ sílẹ̀ gbọdọ̀ jẹ́ òtítọ́. Ohun tí a ń pe ní ìhànde (notability) àti àìṣègbè (neutrality) ni kò ní ìtumọ̀ kan náà láàrín àwùjọ àwọn aláfikún sí ìṣẹ́ Wikimedia, amọ̀ èrò wa ni wípé yóò jẹ́ atọ́nà wọn láti ìmọ̀ tó jẹ́ ojúlówó sílẹ̀. Àjọ Wikimedia kìí fi òtítọ́, àgbéyẹwò láàrín ara-ẹni àti ìgbàwọlé kókó ọ̀rọ̀ ṣe àwàdà rárá. Bẹ́ẹ̀ sínú wọ́n ma ń yàgò fún èrò ara-ẹni àti gbogbo ohun ro le fúni ṣìnà látara àìṣòdodo.
Láfikún sí àwọn àlàkalẹ̀ mẹ́tẹ̀ẹ̀ta wọ̀nyí, ìwé yí ṣàdáyanrí kókó pàtàkì tí ó wà láàrín gbùngbùn ìṣàkóso ara-ẹni tó dára. Àwọn kókó pàtàkì náà ni:
Òmìnira
Gnogbo àwùjọ Wikimedia ni wọ́n ń sapá láti wà lómìnira kí wọ́n lè láfojúsùn tó péye nípa bí ìmọ̀-ọ̀fẹ́ yóò ṣe gbẹ̀rẹ̀jigẹ̀, tí wọn yóò sì yàgò fún èrò tàbí ifẹ́ ọkàn ara-ẹni tí ó lè da iṣẹ́ náà rú. Àjọ Wikimedia ni kò fàyè gba kí ìṣèlú, ọrọ̀-ajé, okòwò tàbí ìgbéga ẹ̀tànjẹ ó rubò wọ́n lójú débi tí wọn yóò wá fi yà bàrà kúrò níbi àfojúsùn wọn.
Ìṣedéédé
Àjọ Wikimedia ni ó mọ wípé gbogbo àwùjọ àwọn aláfikún ìmọ̀-ọ̀fẹ́ Wikimedia káàkiri àgbáyé ni ìmọ̀ wọn kò dọ́gba bákan náà. Ìdí nìyí tí wọ́n fi ń sapá láti kún àwọn aláfikún wọ̀nyí lápá láti jẹ́ kí ìmọ̀ wọn jẹ́ ìkan nípa ìtàn, ìṣèlú, àti àwùjọ wọn. Àjọ Wikimedia ni wọ́n ń gbé ìgbésẹ̀ akin láti kò àwọn ìmọ̀ orísiríṣi jọ láti mú itẹ̀síwájú bá ìṣe déédé ìmọ̀ nípa kí wọn ó jọ máa kẹ́kọ̀ọ́pọ̀ nípa iṣẹ́ wọn.
Ìkójọpọ̀
Àwọn iṣẹ́ àkànṣe tí àjọ Wikimedia ń ṣe ni wọ́n gbé kalẹ̀ ní èdè orísiríṣi kí ó lè ṣàfihàn àṣà ati agbègbè kọ̀ọ̀kan hàn. Gbogbo iṣẹ́ wọ̀nyí tí wọ́n gbé kalẹ̀ bí a ti sọ ṣáájú wọ̀nyí ni wọ́n fi ń bọ̀wọ̀ fún gbogbo elédè kọ̀ọ̀kàn tí wọ́n ṣàfikún sí iṣẹ́ Wikimedia. Ibọ̀wọ̀fún yí ni wọ́n ṣe ní dandan láti lè ró ìkójọpọ̀ lágbára. Àjọ Wikimedia ni wọ́n fàyè sílẹ̀ fún gbogbo mùtúmùwà tí wọ́n bá nífèé sí lè darapọ̀ mọ́ wọn láti jọ ṣagbékalẹ̀ ìmọ̀. Bẹ́ẹ̀ náà ni àjọ yí ṣe mú ìkójọpọ̀ lọ́kùnúnkúndùn fún itẹ̀siwajú ìmọ̀-ọ̀fẹ́ pẹ̀lú ìrànlọ́wọ́ tẹkinọ́lọ́jì.
Ààbò
Àbò gbogbo aláfikún síṣẹ́ ọ̀fẹ́ Wikimedia ni ó ṣe pàtàkì sí wọn. Ìwúrí àjọ Wikimedia ni láti ri wípé àwùjọ wọn wà lálàáfíà kí ìbọ̀wọ̀fún, ìkójọpọ, ìṣedéédé ati Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ ó lè dúró sínsín kí ìmọ̀-ọ̀fẹ́ lè fẹsẹ̀múlẹ̀ lórí ẹ̀rọ ayélujára. Ojúṣe àjọ Wikimedia ni láti ri wípé ààbò wà fún gbogbo aláfikún yálà lórí ẹ̀rọ ayélujára ni tàbí bẹ́ẹ̀kọ.
Ìjíyìn
Àjọ Wikimedia ni ó farajìn látara àwùjọ àwọn aláfikún tí ó bá ń ṣojú wọn. Ìjíyìn yí ni ó dúró lé ìjíròrò, ìpinnu ṣíṣe, ìjábọ̀ iṣẹ́ àkànṣe, ìfiléde ati Ìmọrírì jíjíyìn.
Ìfaradà
Pẹ̀lú ìsọdọ̀tun àfojúsùn, ìwádí ọ̀tun àti ìdánwò orísiríṣi ni ajọ Wikimedia fi ń tẹ̀ siwájú láìfí inọ̀wọ̀fún kókó iṣẹ́ wọn sẹ́yìn pàá pàá jùlọ nínú ìwé yí. Orísiríṣi ìlànà ọ̀tun ni ajọ Wikimedia sì ń lò láti fi mú èròngbà wọn ṣẹ.
Àwọn aláfikún
Àwọn aláfikún ni wọ́n jẹ́ gbòngbò fún àjọ Wikimedia. Ẹnikọ̀ọ̀kan ni ó ní ore-ọ̀fẹ́ ati ànfaní láti ṣàfikún ìmọ̀, iṣẹ́ wọn sí orí pẹpẹ Wikimedia yálà lórí ẹ̀rọ ayélujára tabi láìsí ayélujára. Oníṣẹ́ aláfikún lè dá ìmọ̀-ọ̀fẹ́ sílẹ̀, ó lè ṣe àbójútó rẹ̀, ó lè kópa nínú àwùjọ gẹ́gẹ́ bí ọmọ ẹgbẹ́, ó lè ṣagbátẹrù fún isẹ́ àkànṣe pàtàkì nínú àwùjọ Wikimedia.
Àwọn aláfikún ọ̀fẹ́
Ẹnikẹ́ni tí ó jẹ́ aláfikún ọ̀fẹ́ kìí retí láti gba owó ọ̀yà fún iṣẹ́ rẹ̀ tí ó bá gbéṣe, amọ́ṣá, ó lè rí ìrànwọ́ lóríṣirí gbà kí iṣẹ́ rẹ̀ ó lè kẹ́sẹ-járí. Oníṣẹ́ ọ̀fẹ́ lè ní ànfaní sí onírúurú ìmọ̀ tí wọ́n ti kójọ tí ó lè ràn án lọ́wọ́ láti ṣàṣeyege.
Ẹnikẹ́ni tí ó bá wù láti farajìn fún iṣẹ́ ọ̀fẹ́ ni àyè wà fún láti ṣe bẹ́ẹ̀ níwọ̀n ìgbà tí ó bá ti rọrùn fún un.
Àwọn ẹ̀tọ́
- Aláfikún ọ̀fẹ́ ní ẹ̀tọ́ sí kí a dáàbò bò wọ́n kúrò lọ́wọ́ ìwọ̀sí àti ẹ̀gbin yálà níbi ìpàdé orí ẹ̀rọ ayélujára ni tàbí ti ojúkojú tí àjọ Wikimedia bá gbé kalẹ̀. A ń ṣe eléyí nípa lílo Universal Code of Conduct (UCoC).
- Aláfikún ọ̀fẹ́ ní ẹ̀tọ́ láti kópa nínú iṣẹ́ àkànṣe àti nínú àwùjọ wọn ní gbogbo ọ̀nà. Bákan náà ni wọ́n sì ní ẹ̀tọ́ láti takété tàbí kóraró níbi iṣẹ́ àkànṣe kan lásìkò tí ó bá wù wọ́n.
OlÀwọn ojúṣe
- Gbogbo aláfikún ọ̀fẹ́ gbọdọ̀ tẹ̀lé àwọn ìlànà àátọ̀ tí a ti gbé kalẹ̀ ní gbogbo ìgbà tí wọ́n bá ń ṣiṣẹ́ ọ̀fẹ́ wọn lọ́wọ́.
- Gbogbo aláfikún pátá ni wọn yóò dáhùn fún gbogbo àfikún wọ tí wọ́n bá ṣe.
Àwùjọ àwọn aláfikún
Àwùjọ àwọn aláfikún ni akójọpọ̀ àwọn ènìyàn tí wọ́n jọ ń ṣàfikún sí ìmọ̀-ọ̀fẹ́ yálà lórí ẹ̀rọ ayélujára ni tàbí lókukojú láti ṣe agbátẹrù fún ìmọ̀ òfinẹ́ gẹ́gẹ́ bí àfojúsùn àjọ Wikimedia. Irúfẹ́ àwùjọ bẹ́ẹ̀ lè jẹ́ ẹyọ ènìyàn kan, òṣìṣẹ́ fún àjọ Wikimedia, àwọn aṣojú adari àwùjọ kọ̀ọ̀kan tí àfojúsùn wọn náà bá ti àjọ Wikimedia. Àwọn àwùjọ yí lè jẹmọ́ ède tàbí iṣẹ́ àkànṣe, ìmọ̀ ẹ̀rọ. Gbogbo apápọ̀ àfikún àwọn oníṣẹ́ ọ̀fẹ́ yí ni ó ń di àjọ Wikimedia gan an fúnra rẹ̀.
Àwùjọ àwọn aláfikún nípa ìmọ̀-ẹ̀rọ ni wọ́n ní ànfaní láti ṣagbékalẹ̀ òfin àti ìlànà àátọ̀ tí yóò bá iṣẹ́ wọn mu, níwọ̀n ìgbà tí ìlànà náà bá ti wà ní ìbámu pẹ̀lú ìwé àdéhùn yí ti àjọ Wikimedia Foundation gbé kalẹ̀[1] agbékalẹ̀ ìlànà yí ni ó fún irúfẹ́ àwọn àwùjọ yí ní ànfaní láti ṣètò ara wọn. [2] nípa ìṣàkóso àti iṣẹ́ wọn kí àwọn àwùjọ aláfikún tókù lè báwọn dòwòpọ̀. [3]
Àwọn ẹ̀tọ́
- Àwùjọ àwọn aláfikún ìmọ̀-ẹ̀rọ ní ẹ̀tọ́ láti ṣàfikún tàbí àyọkúrò sí 1àfikún tí ẹnìkanọ̀ọ̀kan wọn. Ìlànà kárí-ayé tí ó ní agbékalẹ̀ ẹ̀tọ́ ni ó fìdí ẹ̀tọ́ yí múlẹ̀.
- Àwọn àwùjọ Wikimedia ló ní ojúṣe láti ṣe ìyípadà sí àwọn ọ̀nà tí wọ́n ń gbà yanjú àwọn awuyewuye àti ìfiwéra wọn lápapọ̀ àti ní ìbámu pẹ̀lú àwọn ìlànà àgbáyé. [4]
Àwọn ojúṣe
- Àwọn àwùjọ aláfikún Wikimedia gbọ́dọ̀ lè kò àwọn ènìyàn wọn mọ́ra láti báwọn kópa nínú iṣẹ́ ati ìṣàkóso wọn. Ẹnikẹ́ni tí ó bá ní àyè ati ìmọ̀ tí lè fi kópa ni kí wọ́n gbà láàyè kí ó dásí.
- Gbogbo àwùjọ àwọn aláfikún ni ó gbọ́dọ̀ ma ṣe déédé ati dọ́gba-n-dọ́gba níbi ìṣàkóso ati ìlò òfin wọn kí ó lè wà níbàámu pẹ̀lu ti àjọ Wikimedia.
- Àwọn ètò ati ìlànà àátọ̀ àwọn àwùjọ wọ̀nyí ni wọ́n gbọ́dọ̀ wà ní arọ́wọ́tó gbogbo àwùjọ wọn, kí ó sì ṣeé múlò pẹ̀lú.
Àwọn ẹ̀ka Àjọ Wikimedia
Àwọn olùyọ̀ǹda ara ẹni àti àwọn àwùjọ Wikimedia Movement ń dá àwọn àjọ sílẹ̀ láti ṣètìlẹ́yìn fún àti ṣètò àwọn ìgbòkègbodò wọn. Nínú Àpínlẹ̀ yìí, àwọn àjọ wọ̀nyí ni a ń pè ní Àwọn Ẹ̀yà Ìṣèlú Wikimedia, èyí tó ní àwọn Ẹ̀ka Ìṣèlù Wikimedia, Ìpínlẹ́ Wikimedia, àti Ìgbìmọ̀ Àgbáyé. Ìgbìmọ̀ Àgbáyé àti Ìpínlẹ̀ Wikimedia ni àwọn ìgbìmọ̀ tó ga jù lọ tó ń ṣàkóso, àwọn méjèèjì ní àwọn àfojúsùn àti ojúṣe pàtó tiwọn.
Kí àwọn aláfikún tí wọn kò ní ìkúnlápá tó ó lè ma kópa nínú àwọn iṣẹ́ àkànṣe Wikimedia orísiríṣi láìsí ìṣòro. Àwọn àwùjọ aláfikún Wikimedia kò ní agbára lórí èyíkéyí iṣẹ́ àkànṣe Wikimedia àti àwọn àkóónú inú wọn. Gbogbo àwùjọ Wikimedia pátá ni wọ́n ní ànfaní láti ní Jàre Responsibility nípa àwùjọ àwọn aláfikún Wikimedia tí wọ́n bá wà.
Àwọn Ìlànà ìparí ìjà ni wọ́n lè[5]. Ni wọ́n lè lò láti fi ma pari ìjà tàbí aáwọ̀ tí ó bá le koko. Àjọ Wikimedia ni wọn yóò ma lo òfin yí àti àwùjọ àwọn aláfikún tí wọ́n bá tún fún nírú ànfaní bẹ́ẹ̀.
Àwùjọ àwọn aláfikún Wikimedia
Wikimedia Movement Organizations are organized groups that exist to create conditions for open and free knowledge to flourish in a given geographic or thematic context. Wikimedia Movement Organizations operate in line with the Wikimedia Movement’s vision, and include Wikimedia affiliates, hubs, and other groups that the Global Council[6] or its appointed committees have recognized formally.
There are four different types of Wikimedia Movement Organizations:
- Wikimedia Chapters are affiliates that are independent organizations founded to support and promote the Wikimedia projects in a specified geographical region.
- Wikimedia Thematic Organizations are affiliates that are independent organizations founded to support and promote Wikimedia projects within a specific topic or focus.
- Wikimedia User Groups are simple and flexible affiliates that can be organized by region or theme.
- Wikimedia Hubs are organizations formed by affiliates for regional or thematic[7] support, collaboration and coordination.
Wikimedia Movement Organizations are a key way in which Wikimedia Movement communities can organize within the Wikimedia Movement for delivery of activities and cooperative endeavors. Wikimedia Movement Organizations may employ professionals to support the mission of the organization, as well as the free knowledge vision. Most often, this support is provided by amplifying and supporting the work of volunteers.
Governance
Guided by Movement Values, Principles of Decision-Making, and standards established by the Global Council, the body of a Wikimedia Movement Organization can decide its composition and governance according to the context and needs within which it operates. The decision-maker in a Wikimedia Movement Organization is an organization’s board or a similar body and is accountable to the group that such board or similar body represents—for example, its membership body.
Responsibilities
The responsibilities of Wikimedia Movement Organizations include:
- promoting the sustainability of Wikimedia Movement communities that the membership body intends to support;
- facilitating inclusion, equity, and diversity within their community;
- upholding the Universal Code of Conduct (UCoC); and
- developing partnerships and collaborations within their areas of interest.
For numerous reasons, including the resource allocation within the Wikimedia Movement, Wikimedia Movement Organizations should make their work and activities transparent by providing publicly accessible reporting.
Wikimedia Movement Organizations may choose to develop their financial sustainability through additional revenue generation, thereby increasing the overall capacity of the Wikimedia Movement. When necessary, such efforts for revenue generation must be coordinated with other Wikimedia Movement Bodies, including the Wikimedia Foundation and the Global Council.
Wikimedia Foundation
The Wikimedia Foundation (WMF) is the nonprofit organization that serves as the main steward and support of the Wikimedia Movement’s free knowledge platforms and technology. The mission of the Wikimedia Foundation is to empower and engage people around the world to collect and develop educational content under a free license or in the public domain, as well as to disseminate it effectively and globally.
The Wikimedia Foundation should align its work with the strategic direction and global strategy of the Global Council. Following the Movement Values and Principles of Decision-Making, and the WMF’s mission, the Wikimedia Foundation is expected to contribute to distributed leadership and responsibilities across the Wikimedia Movement. For the same reasons, the Wikimedia Foundation is also expected to work towards equitable distribution of resources, such as those established by the Global Council in consultation with stakeholders.
Governance
Guided by Movement Values and Principles of Decision-Making, the Wikimedia Foundation can decide its composition and governance in accordance with this Charter, and the context and needs within which it operates. The Wikimedia Foundation works closely with the Global Council, especially on matters that have global or movement-wide impact on the Wikimedia Movement.
Responsibilities
The Wikimedia Foundation’s responsibilities include, but are not limited to:
- Operating the Wikimedia projects, which includes hosting, developing, and maintaining core software; setting Terms of Use and other broad movement-wide policies; running fundraising campaigns; respecting and supporting community autonomy and stakeholder needs; and engaging in any other actions so that Wikimedia projects are easily accessible available and vision-aligned;
- Supporting programmatic activities for the Wikimedia Movement; and
- Legal obligations, including stewarding the Wikimedia brand; providing policies that provide a structure so as allow projects to run; ensuring legislative compliance; addressing legal threats; and enhancing safety of volunteers.
Global Council
The Global Council[8] is a collaborative and representative decision-making body that brings together diverse viewpoints to advance the vision of the Wikimedia Movement. The Global Council operates alongside the Wikimedia Foundation and other Wikimedia Movement Organizations to foster an inclusive and effective environment for the Wikimedia Movement as a whole and for all stakeholders involved.
Purpose
The Global Council serves as a forum where different Wikimedia Movement perspectives converge, thereby playing a pivotal role in shaping the future trajectory of the Wikimedia Movement. The Global Council seeks to ensure the continued relevance and impact of the Wikimedia Movement in an ever-changing world through its functions of strategic planning, support of Wikimedia Movement Organizations, resource distribution, and technology advancement.
Decisions are better informed and reflect the needs and priorities of the global community when a wide range of voices and experiences from across the Wikimedia Movement represent and participate in the highest levels of decision-making. By electing and selecting a majority of the Global Council’s members from the Wikimedia Movement’s volunteer base, the Global Council fosters a stronger sense of ownership and trust, while working towards the Wikimedia Movement’s vision of free knowledge. To support inclusion and representation of diverse perspectives, the membership of the Global Council should not be dominated by any particular demographic, including, but not limited to, any linguistic, geographical, or project-based demographic.
Governance
Guided by Movement Values and Principles of Decision-Making, the body of the Global Council can decide its composition and governance in accordance to the context and needs within which the Global Council operates. The Global Council also decides on the details of its own procedures. These procedures include, but are not limited to: the Global Council structure, membership, decision-making processes, responsibilities and accountability, and mechanisms for the inclusion of new and less-heard voices.
Functions
The Global Council focuses on four functions and areas of decision-making that have a direct impact on the Wikimedia Movement community and stakeholders. The Global Council has decision-making authority over all of its functions established by this Charter. The members of the Global Council are held accountable for the decisions and actions of the Global Council through the election and selection process.
The Global Council elects a Global Council Board, which is in charge of coordinating[9] and representing the Global Council as mandated by this Charter and the Global Council’s decisions. The Global Council Board approves the establishment and activities of the Global Council committees and their membership. These Global Council committees determine their own composition and ways of operating, and can appoint additional members who are not members of the Global Council to contribute to their work. The Global Council has at least four committees, individually responsible for each of the four functions outlined in this Charter.
Strategic Planning
The Global Council is responsible for developing long-term strategic[10] direction for the Wikimedia Movement. The strategic direction will serve as a foundation for decisions made by the Global Council and as guidance for the prioritization of the initiatives to achieve strategic goals. All Wikimedia Movement Bodies are expected to support the strategic direction established by the Global Council and incorporate it into their programs and activities. Based on such strategic direction, the Global Council also develops recommended annual global strategic priorities for the Wikimedia Movement. The Global Council develops the strategic direction in consultation with all stakeholders inside and outside the Wikimedia Movement.
Support of Wikimedia Movement Organizations
The Global Council establishes standards for the functioning of Wikimedia affiliates[11] and Wikimedia hubs. To achieve this, the Global Council and its committee establish and oversee processes for recognition/derecognition of these affiliates and hubs;[12] seek to ensure that Wikimedia Movement Organizations are in compliance with organizational standards; facilitate conflict resolution to maintain collaborative and respectful relationships within the Wikimedia Movement; and simplify access to resources (financial, human, knowledge, and others) for more equitable support and empowerment of Wikimedia Movement communities.
Resource Distribution
The Global Council establishes and periodically reviews the standards and guidelines for the equitable distribution of the funds[13] in the Wikimedia Movement in alignment with the strategic direction. These standards and guidelines shall comply with the Principles of Decision-Making. Furthermore, the Global Council and its committees determine the grant distribution to the Wikimedia Movement communities and Wikimedia Movement Organizations; determine movement-wide goals and metrics in conformity with the priorities set out in the strategic direction; determine the regional, thematic, and other funding allocations; and review global programmatic outcomes.[14]
Technology Advancement
The Global Council coordinates across different Wikimedia Movement technology-focused stakeholders,[15] and provides advice and guidance on technological advancement. The Global Council assists and advises the Wikimedia Foundation in prioritizing technological changes,[16] including the opening or closing of Wikimedia language projects, and helps the wider Wikimedia Movement understand the technological priorities as set forth in the strategic direction. The Global Council will exercise these functions in collaboration with Wikimedia Movement Bodies and online technical contributors.[17][18]
Initial creation and future expansion
The first Global Council will have twenty-five members. Of which, twelve members will be elected by the Wikimedia community at large; eight members will be selected through Wikimedia affiliates; one by the Wikimedia Foundation; and the remaining four members will be directly appointed by the Global Council, for the purpose of increasing expertise and diversity within its membership.
The Global Council selects twenty-percent (20%) of its members to serve on the Global Council Board.
With the experiences gained through its initial set-up and processes, the Global Council will review internal workings and mechanisms in order to innovate, adapt, and grow as a Wikimedia Movement Body. At least once every 3 years:
- The Global Council, in collaboration with Wikimedia Movement stakeholders, conducts an evaluation of its functioning. The evaluation will include a review of whether an expansion of the Global Council’s functions and its scope for decision-making is advisable and feasible within the following Global Council term.
- The Global Council reviews the Wikimedia Movement’s needs to determine whether the current membership size of the Global Council is compatible with its responsibilities. The Global Council may decide to expand or contract its size as a result of this review. The Global Council can have a maximum of 100 members.
- If the Global Council and other stakeholders choose to increase the membership size of the Global Council to gradually build up a broader base of diversity and experience, it may do so at intervals of up to 25 more members every 18 months until the Global Council reaches 100 members.
Amendment
This Charter is designed to endure for many years. Because of this, except as provided below, amendments to this Charter are to be made only in extraordinary circumstances.
Categories of amendments
- Minor corrections.
- Spelling and grammar corrections that do not change the meaning or intent of this Charter.
- Changes to this Charter that affect only the working processes of the Global Council.
- Changes to this Charter that:
- Modify the overall responsibilities and membership of the Council.
- Modify the values of the Wikimedia Movement; or the responsibilities and rights of individual contributors, projects, affiliates, hubs, the Wikimedia Foundation, future Wikimedia Movement Organizations, and the wider Wikimedia Movement.
- Changes proposed by the Wikimedia Movement.
Amendment Category | Process | Change Approval Body | Notes |
1 | 55% support for proposed change | Global Council Board | |
2 | 55% support for proposed change | Global Council | Community consultation recommended |
3 | Movement-wide vote, 55% support for change | Wikimedia Movement | Voting mechanism to follow the ratification process as closely as possible, including support vote from the Wikimedia Foundation Board of Trustees |
4 | Proposals must meet criteria to move on to voting. Movement-wide vote, 55% support for change | Wikimedia Movement | Voting mechanism to follow the ratification process as closely as possible, including support vote from Wikimedia Foundation Board of Trustees |
Process for proposing Wikimedia Movement Charter amendments
The Global Council Board may propose amendments in Categories 1, 2, and 3. The Global Council may propose amendments in Categories 2 and 3. Category 4 amendments are proposed by members of the Wikimedia Movement. Category 4 amendments must meet certain criteria, including public support in order to trigger the amendment voting process. The Global Council is responsible for designing the process in consultation with the Wikimedia community.
The Global Council must appoint an independent committee to manage voting on Categories 3 and 4 amendments. The Global Council may define voting eligibility criteria for affiliates and individual voters, or may delegate this responsibility to the independent committee.
Ratification
The Charter is ratified and comes into effect after a vote that has the following result:
- 55% support from participating Wikimedia affiliates, with a minimum of half (50%) of eligible affiliates participating in the vote;
- 55% support from participating individual voters,[19] with a minimum of 2% of eligible voters participating in the vote; and
- The Wikimedia Foundation Board of Trustees votes to support the Charter.
Prevailing language and translations
Translations of this Charter may be provided in other languages. In the event of doubt or conflict between any translation and the original English language version, the English language shall prevail.
Notes
- ↑ framework of global policies include those documented here and here, such as the Terms of Use for the Wikimedia project websites.
- ↑ Irúfẹ́ àwùjọ yí gbọ́dọ̀ kò àkóyawọ́ nípa ìlànà àátọ̀ wọn fún ìgbéyàwó gbogbo ọmọ ẹgbẹ́.
- ↑ Èyí túmọ̀ sí wípé àwọn tó bá farahàn láti gbé ìpinnu kalẹ̀ yálà nípa ìṣètò ni tàbí ìlànà àátọ̀.
- ↑ Àwọn ìlànà Ìpínlẹ̀-ìpínlẹ́ kò lè ta ko àwọn ìlànà àgbáyé tàbí àwọn ojúṣe òfin.
- ↑ ni wọ́n lè dásílẹ̀ nígbà tí wọ́n bá ti fẹsẹ̀ rẹ̀ múlẹ̀
- ↑ Prior to the start of and transition period of the Global Council, Wikimedia Movement Organizations are recognized by the Wikimedia Foundation Board of Trustees.
- ↑ This Charter sees Language Hubs as a form of Thematic Hub.
- ↑ In line with the legal reviews received in 2023 for this Charter, the Global Council will initially not be set up as a legal entity.
- ↑ The Global Council Board is the body tasked with: making sure the processes within the Global Council are running according to plans and timelines; coordinating with others where and when necessary; ensuring that the Global Council is operating and functioning according to its purpose; and other similar tasks.
- ↑ Strategy is inclusive of major projects to change the Wikimedia brand.
- ↑ This is meant to be inclusive of the functions held by the Affiliations Committee (AffCom) prior to the creation of the Global Council.
- ↑ The trademark licensing and contractual agreement components related to this process remains a responsibility of the Wikimedia Foundation.
- ↑ This refers to the movement-wide allocation of funds.
- ↑ This is meant to be inclusive of the functions currently held by the Regional Fund Committees prior to the creation of the Global Council.
- ↑ Stakeholders include contributors, Wikimedia Foundation, affiliates, hubs and more.
- ↑ A Memorandum of Understanding-like or Service Level Agreement-like document will be created between the Wikimedia Foundation and Global Council to lay out the agreement for how they work together, including how Global Council suggestions are received by the Foundation.
- ↑ This Global Council committee is meant to reflect the Movement Strategy Initiative for a Technology Council.
- ↑ Final technological prioritization decisions will be taken by the bodies primarily dedicated to the delivery of products and technology services, along with the appropriate community-led movement body associated with the Global Council.
- ↑ Individual voters, for the purpose of the ratification process, are individuals who would normally be eligible to vote in elections to select Wikimedia Foundation Board of Trustees members.