Ìṣèlú àti Ìṣàkóso Ìyípadà/Àtúlẹ̀/Àtẹ̀sílẹ̀
Outdated translations are marked like this.
A
Gẹ̀ẹ́sì | Ìtúmọ̀ |
---|---|
abuse filter | aṣẹ́ ìlòkulò |
accountability | ètò-ìṣirò |
admin | alákoso |
administrator | alákoso |
administrators | àwọn alákoso |
administrators on meta | àwọn alákoso lórí meta |
adminship | ìṣàkóso |
advanced rights | àwọn ohun-èlò gíga |
advisor | onímọ̀ràn |
Advisory Board | Ìgbìmọ̀ àwọn onímọ̀ràn |
AffCom | AffCom |
affiliate | ẹ̀ka |
affiliates | àwọn ẹ̀ka |
Affiliations Committee | Ìgbìmọ̀ fún àwọn ẹ̀ka |
Africa | Áfíríkà |
arbitration committee | Ìgbẹ́jọ́ lọ s'ókè |
appeal | ìgbẹ́jọ́ |
Assistant election official | Àgbàṣẹ́ tó ń bójú tó àwọn ìdìbò |
autoconfirmed users | àwọn oníṣe tó jẹ́ alájẹ̀múṣẹ |
autopatrolled users | àwọn tó ń ṣe àbójútó àkànṣe |
B
Gẹ̀ẹ́sì | Ìtúmọ̀ |
---|---|
backlog | iṣẹ́ fún ṣíṣe |
best practices | àwọn ìṣe tó dára jùlọ |
board | ìgbìmọ̀ àwọn onígbọ̀wọ́ |
board election | ìdìbò fún ìgbìmọ̀ àwọn onígbọ̀wọ́ |
board elections | ìdìbò fún ìgbìmọ̀ àwọn onígbọ̀wọ́ |
Board Governance Committee | Ẹgbẹ́ ìdarí ìgbìmọ̀ àwọn onígbọ̀wọ́ |
board handbook | ìwé ìlànà ìgbìmọ̀ àwọn onígbọ̀wọ́ |
Board of Trustees | Ìgbìmọ̀ àwọn Onígbọ̀wọ́ |
BoT | Roboti |
bot | roboti |
bylaws | àwọn òfin |
C
Gẹ̀ẹ́sì | Ìtúmọ̀ |
---|---|
Call for feedback | Ìpè fún èsì |
candidate | olùdíje |
candidates | àwọn olùdíje |
category | ẹ̀ka |
CEE | CEE |
Central and Eastern Europe | Àárín Gbùngbùn àti Ìlà Oòrùn Yúróòpù |
Central and Eastern Europe (CEE) and Central Asia | Àárín Gbùngbùn Àríwá àti Ìlà Oòrùn Yúróòpù (CEE) àti Àárín Gbúngbà Àríwá Éṣíà |
CentralNotice | Ìròyìn Àkànṣe |
chair | alágàa |
Chairman Emeritus | Alaga Emeritus |
challenge | ìpèníjà |
change | àtúnṣe |
changes | awọn àtúnṣe |
chapter | ẹ̀ka t'onipín Wikimedia |
chapters | àwọn ẹ̀ka t'onipín Wikimedia |
chapters agreement | adéhùn àwọn ẹ̀ka t'onipín Wikimedia |
Chapters committee | Ìgbìmọ̀ àwọn ẹ̀ka t'onipín Wikimedia |
chapters handbook | iwé-ìlànà àwọn ẹ̀ka t'onipín Wikimedia |
Chapters meeting | Ìpàdé àwọn ẹ̀ka t'onipín Wikimedia |
Charter | Ìwé-àdéhùn |
Charter content | Ọ̀rọ̀ ìwé-àdéhùn |
Charter drafting | Kíkọ ìwé-àdéhùn |
CheckUser | CheckUser |
CheckUser policy | ṢayẹwoIṣakoso olumulo |
Chief Operational officer | Olórí Òṣìṣẹ́ fún Àwọn Iṣẹ́-ṣíṣe |
Chief Technical Officer | Olórí Òṣìṣẹ́ fún Ìmọ̀-ẹ̀rọ |
ComCom | ComCom |
commission | ìgbìmọ̀ |
committee | ìgbìmọ̀ |
Commons | Àwọn aráàlú |
Communications committee | Ìgbìmọ̀ fún ìbáraẹnisọ̀rọ̀ |
communities | àwọn ará àjọṣepọ̀ |
communities and organizations | àwọn ará àti àjọ àjọṣepọ̀ |
community | ará àjọṣepọ̀ |
Community Affairs Committee | Ìgbìmọ̀ fún Àlámọrí àwọn Ará Àjọṣepọ̀ |
Community Development | Ìdàgbàsókè àwọn Ará Àjọṣepọ̀ |
Community Development team | Ẹgbẹ́ Ìdàgbàsókè àwọn Ará Àjọṣepọ̀ |
community meeting | Ìpàdé àwọn ará àjọṣepọ̀ |
Community Resilience and Sustainability (CR&S) | Àgbéró àti Ìpẹ́láyé àwọn Ará Ajọṣepọ̀ |
conflict of interest | ìtakò ànfààní |
consensus | ìpohùnpọ̀ |
consultation | ìkànsí |
consultation with | ikànsí pẹ̀lu |
consultation with communities | ìkànsí pẹ̀lu àwọn ará àjọṣepọ̀ |
consultations | àwọn ìkànsí |
content | ọ̀rọ̀ |
contractor | agbaṣẹ́ṣe |
contributor(s) | (àwọn) olùdásí |
conversation | ìjíròrò |
conversations | àwọn ìjíròrò |
coordinating | nṣ'ètò |
coordination | ìṣètò |
Council | Ìgbìmọ̀ |
D
Gẹ̀ẹ́sì | Ìtúmọ̀ |
---|---|
desktop | tabili kọmputa |
development | ìdàgbàsókè |
development of | ti ìdàgbàsókè |
Diff blog | Búlọ́ọ̀gì diff |
Direction | Ìtọ́sọ́nà |
disambiguation | àtúpalẹ̀-ọ̀rọ̀ |
discussion | ìjíròrò |
discussion page | ojú-ewé ìjíròrò |
Discussion Tools | Ohun-èlò fún Ìjíròrò |
discussions | àwọn ìjíròrò |
diverse | onírúurú |
diversity | onírúurú |
draft | ọ̀rọ̀-àkọ́kọ́ |
drafting | kíkọ |
Drafting committee | Ìgbìmọ̀ fún kíkọ |
drafts | àwọn ọ̀rọ̀-àkọ́kọ́ |
E
Gẹ̀ẹ́sì | Ìtúmọ̀ |
---|---|
East, Southeast Asia, and Pacific | Ìlà Oòrùn, Gúúsù Ìlà Oorun Éṣíà àti Òkun Pàsífíìkì |
edit conflict | rògbòdìyàn àtúnṣe |
edit summary | àkótán àtúnṣe |
edit war | ìjà lórí àtúnṣe |
Edit-a-thon | Ṣàtúnṣe-à-à-ìwé |
Editathon | Awọn atunkọ |
editing | nṣ'àtúnṣe |
editor | olóòtú ṣiṣatunkọ |
editors | àwọn olóòtú ṣiṣatunkọ |
election | ìdìbò |
Election compass | Atọ́ka ìdìbò |
Election officers | Àwọn òṣìṣẹ́ fún ètò ìdìbò |
election volunteer | olùfarajìn fún ètò ìdìbò |
elections | àwọn ìdìbò |
Elections Committee | Ìgbìmọ̀ elétò Ìdìbò |
Embassies | Awọn ile-iṣẹ ijọba ajeji |
Embassy | Ile-iṣẹ ijọba ajeji |
emerging communities | àwọn ará àjọṣepọ̀ tó ṣẹ̀ nyọjú |
emerging community | ará àjọṣepọ̀ tó ṣẹ̀ nyọjú |
employee | òṣìṣẹ́ |
employees | àwọn òṣìṣẹ́ |
enforcement | ìgbófìnró |
Enforcement Guideline | Ìlànà ìgbófìnró |
Enforcement Guidelines | Àwọn ìlànà ìgbófìnró |
ESEAP | ESEAP |
Europe | Yúróòpù |
evaluation | ìgbéléwọ̀n |
event | ìpèjọ |
events | àwọn ìpèjọ |
Events committee | Ìgbìmọ̀ fún àwọn ìpèjọ |
Executive Director | Olùdarí Àgbà |
extension | itẹsiwaju |
external links | àwọn ìjápọ̀ àgbáyé |
F, G
Gẹ̀ẹ́sì | Ìtúmọ̀ |
---|---|
FDC | FDC |
feature | ẹya-ara |
financial committee | igbìmọ̀ fún ètò ìsúná |
financial reports | àwọn ìjábò ètò ìsúná |
Foundation | Ìpínlẹ̀ |
Foundation-l | Àtìlé-1 |
free knowledge | imọ̀ ọ̀fẹ́ |
fund | owó |
Fundraising committee | Ìgbìmọ̀ ìkówójọ |
funds | àwọn owó |
Funds Dissemination Committee | Ìgbìmọ̀ ètò Ìnáwó |
General Counsel | Amòfin àgbà |
Gerrit | Gerrit |
GFDL | GFDL |
GLAM | GLAM |
GLAMs | Àwọn GLAM |
GLAMwiki conferences | Àwọn àpèjọ-nlá fún GLAMwiki |
global conversation | ìjíròrò káríayé |
global conversations | àwọn ìjíròrò káríayé |
Global council | Ìgbìmọ̀ káríayé |
global permissions | àwọn ìgbàláàyè káríayé |
global policies | àwọn òfin tó káríayé |
global policy | òfin tó káríayé |
Global Sysop | Syop tó káríayé |
Global Sysops | Àwọn Syop tó káríayé |
governance | ètò ìjọba |
Governance review | Àtúnyẹ̀wò ètò ìjọba |
grant | fifunni |
Grant Advisory Committee (GAC) | Ìgbìmọ̀ Ìdámọ̀ràn fún fifunni (GAC) |
grantee | olùgb'owó |
grants | grant |
guideline | ìlànà |
H, I , K
Gẹ̀ẹ́sì | Ìtúmọ̀ |
---|---|
hackathon | ìsọfúnni |
healthy community | àjọṣepọ̀ tí ìlera rẹ̀ péye |
helpdesk | tábìlì-ìrànlọ́wọ́ |
home wiki | wiki orísun |
hub | ibùdó |
hubs | àwọn ibùdó |
implement | ìmúṣe |
implementation | ètò-ìmúṣe |
inclusive | ní onírúurú |
initiative (Movement Strategy Initiative) | initiative |
insurance committee | ìgbìmọ̀ ìṣèdúró |
interface | ojú-ìwò |
interface administrator | alákòso ojú-ìwò |
interfaces | àwọn alákòso ojú-ìwò |
Interim Global Council | Adelé Ìgbìmọ̀ Káríayé |
interwiki | interwiki |
IRC | IRC |
knowledge | ìmọ̀ |
L
Gẹ̀ẹ́sì | Ìtúmọ̀ |
---|---|
LangCom | LangCom |
Language Committee | Ìgbìmọ̀ Èdè |
LATAM | LATAM |
Latin America | Latin America |
Latin America (LATAM) and The Caribbean | Latin America (LATAM) àti Caribbean |
leader | Olórí |
leadership | Ìdarí |
Leadership development | Ìdàgbàsókè ìdarí |
Leadership development working group | Ẹgbẹ́ iṣẹ́ fún ìdàgbàsókè ìdarí |
legal | t'olófìn |
legal officer | Òṣìṣẹ́ t'olófìn |
libraries | àwọn ilé-ìkàwé |
library | ilé-ìkàwé |
list of chapters | àtòjọ àwọn ẹ̀ka t'onipín Wikimedia |
list of projects | àtòjọ àwọn iṣẹ́-àkànṣe |
lists of projects | àtòjọ àwọn iṣẹ́-àkànṣe |
logo | àwòrán-ìdánimọ̀ |
logos | àwọn àwòrán-ìdánimọ̀ |
M, N
Gẹ̀ẹ́sì | Ìtúmọ̀ |
---|---|
mailing list | mailing list |
mailing lists | àwọn mailing list |
main page | ojúewé àkọ́kọ́ |
mainspace | ààyè-gbogboògbò |
maintaining | nṣètọ́jú |
matching fund | owó ìbámu |
MediaWiki | MediaWiki |
MENA | MENA |
Meta policies | Àwọn òfin Meta |
Middle East and Africa | Middle East àti Áfíríkà |
mission statement | ọ̀rọ̀ àfojúsùn |
movement | àjọṣepọ̀ |
Movement Charter | Ìwé-àdéhùn Àjọṣepọ̀ |
Movement Strategy | Strategy Àjọṣepọ̀ |
movement-wide | kárí-Àjọṣepọ̀ |
multilingual project | iṣẹ́-àkànṣe onírúurú-èdè |
multilingual projects | àwọn iṣẹ́-àkànṣe onírúurú-èdè |
namespace | ààyè-ọ̀rọ̀ |
namespaces | àwọn ààyè-ọ̀rọ̀ |
need for leadership | ìní fún ìdarí |
needs | àwọn ìní |
Neutral point of view (NPOV) | Ìrísí Àìlójúṣájú (NPOV) |
newcomer | ẹni titun |
newcomers | àwọn ẹni titun |
O, P
Gẹ̀ẹ́sì | Ìtúmọ̀ |
---|---|
office action | ìgbésẹ̀ ilé-iṣẹ́ |
office actions | àwọn ìgbésẹ̀ ilé-iṣẹ́ |
officers | àwọn òṣìṣẹ́ |
office hour(s) | wákàtí (wákàtí) àwọn òṣìṣẹ́ |
online platform | pẹpẹ ayélujára |
online tool | ohun-èlò ayélujára |
organization | àjọ |
organizations | àwọn àjọ |
outreach | ìpolongo |
oversight | àbójútó |
page | ojúewé |
paid editing | ìṣàtúnṣe t'olówó |
participant | olùkópa |
participants | Àwọn olùkópa |
permissions | àwọn ìgbàláàyè |
platform | pẹpẹ |
platforms | àwọn pẹpẹ |
point of view (pov) | ìrísí (pov) |
policies | àwọn òfin |
policy | òfin |
presentation | àgbéjáde |
presentations | àwọn àgbéjáde |
priorities | ìwò àwọn ohun-pàtàkì |
prioritized | múní pàtàkì-jùlọ |
priority | ohun pàtàkì-jùlọ |
priority initiative | àfojúsùn pàtàkì-jùlọ |
priority initiatives | àwọn àfojúsùn pàtàkì-jùlọ |
privilege | àǹfààní |
process | ètò |
processes | àwọn ètò |
project | iṣẹ́-àkànṣe |
projects | àwọn iṣẹ́-àkànṣe |
proposal | ìbẹ̀wẹ̀ |
proposals | àwọn ìbẹ̀wẹ̀ |
R
Gẹ̀ẹ́sì | Ìtúmọ̀ |
---|---|
random page | ojú-ewé èyíkèyí |
ratification | ìfọwọ́sí |
ratification process | ètò ìfọwọ́sí |
recent changes | ojúṣe |
recommendation | padàsẹ́hìn |
recommendations | owó-ìwọlé |
red link | àwọn owó-ìwọlé |
redirect | Tábílì-ìjíròrò |
Regional hub | SAARC |
Regional hubs | àpótí-àdánwò |
rename | sàkání |
request | yíyàn |
request for permissions | ìwọlé ọ̀kan f'oníṣẹ́ |
requests | ibeere |
requests for permissions | àwọn ìbéèrè fún àṣẹ |
requests for username changes | àwọn ìbéèrè nípa yípa orúkọ oníṣe |
research | Iwadi |
research phase | Ipele iwadi |
research report | ijabọ ìwádì |
research result | àbájáde ìwádì |
resource | ohun ìní |
resources | àwọn ohun ìní |
responsibilities | àwọn ojúṣe |
responsibility | ojúṣe |
retreat | ìtìlẹyìn |
revenue | owó tó ń wọlé |
revenues | àwọn owó tó ń wọlé |
right | ọ̀nà tó tọ́ |
Roundtable | Tabili ìyíká |
S
Gẹ̀ẹ́sì | Ìtúmọ̀ |
---|---|
SAARC | Àwọn aráàlú |
sandbox | àpáta àpáta |
scope | àyè tí wọ́n lè lò |
section | apá |
selection | ìdìbò |
single user login | ìkànnì ìkànnì oníṣe kan ṣoṣo |
sister projects | àwọn iṣẹ́-àkànṣe mìíràn |
skills development | ìdàgbàsókè ìmọ̀ṣe |
Small Wiki Monitoring Team | Ẹgbẹ́ Alámòjútó Àwọn Wiki Kékeré |
South Asian Association for Regional Cooperation | South Asian Association for Regional Cooperation |
spam | ìsọfúnni tí kò tọ́ |
spam block list | Àkọsílẹ ìsọfúnni tí kò tọ́ ti di |
special page | ojú-ewé pàtàkì |
special pages | àwọn ojú-ewé pàtàkì |
speedy deletion | ìparẹ́ ní kánkán |
speedy deletions | àwọn ìparẹ́ ní kánkán |
staff | àwọn òṣìṣẹ́ |
stakeholder | alátìlẹ́yìn |
stakeholders | àwọn alátìlẹ́yìn |
steward | iriju |
steward elections | ìdìbò àwọn iriju |
steward requests | àwọn ohun tí iriju ń béèrè |
stewards | àwọn iriju |
strategy | strategy |
strategy recommendation | ìmọ̀ràn strategy |
strategy recommendations | àwọn ìmọ̀ràn strategy |
SUL | SUL |
summaries | àwọn àkọ́tán |
summary | àkọ́tán |
support | àtìlẹ́yìn |
suppression | ìfòòró |
sustainability | ìpẹ́láyé |
sysop | syop |
sysops | àwọn syop |
T
Gẹ̀ẹ́sì | Ìtúmọ̀ |
---|---|
talk page | ojú-ewé ọ̀rọ̀ |
talk pages | àwọn ojú-ewé ọ̀rọ̀ |
task force | agbófìnró |
Telegram Group | Ẹgbẹ́ Telegram |
Telegram Groups | Àwọn ẹgbẹ́ Telegram |
template | àdàkọ |
templates | àwọn àdàkọ |
test wiki | wiki ìdánwò |
test wikis | àwọn wiki ìdánwò |
thematic hub | ibùdó àkórí |
thematic hubs | àwọn ibùdó àkórí |
thematic organization | àjọ àkórí |
thematic organizations | àwọn àjọ àkórí |
trademarks committee | ìgbìmọ̀ àmì-òwò |
transclusion | àtúpalẹ̀ |
translation of the week | ìtúmọ̀ ti ọ̀sẹ̀ |
translation request | ìbéèrè fún ìtúmọ̀ |
translation requests | àwọn ìbéèrè fún ìtúmọ̀ |
treasurer | akápò |
Trust & Safety | Trust & Safety |
trustee | onígbọ̀wọ́ |
trustees | àwọn onígbọ̀wọ́ |
U, V
Gẹ̀ẹ́sì | Ìtúmọ̀ |
---|---|
UCoC Enforcement guidelines | Àwọn ìlànà ìgbófìnró UCoC |
United States and Canada | United States àti Canada |
Universal Code of Conduct | Àlàkalẹ̀ Gbogboògbò fún Ìhùwàsí |
update | ìmúdójúìwọ̀n |
user | oníṣẹ́ |
user group | ẹgbẹ́ oníṣẹ́ |
user groups | àwọn ẹgbẹ́ oníṣẹ́ |
user page | ojú-ewé oníṣẹ́ |
vandal | onídàrú |
vandalism | ìdàrú |
vandals | àwọn onídàrú |
verifiability | ìwádìí |
vice-chair | igbákejì alága |
village pump | abẹ́ igi |
VisualEditor | VisualEditor |
Volunteer Response Team | Ẹgbẹ́ Olùfarajìn fún Ìdáhùn |
W
Gẹ̀ẹ́sì | Ìtúmọ̀ |
---|---|
Wikibooks | Wikibooks |
Wikicouncil | Wikicouncil |
Wikimania | Wikimania |
Wikimedia | Wikimedia |
Wikimedian | Wikimedian |
Wikimedia Cloud Services (WMCS) | Wikimedia Cloud Services (WMCS) |
Wikimedia Commons | Wikimedia Commons |
Wikimedia community | Àjọṣepọ̀ Wikimedia |
Wikimedia Foundation | Wikimedia Foundation |
Wikimedia Foundation official policies | Àwọn òfin iṣẹ́ Wikimedia Foundation |
Wikimedia Foundation official policy | Òfin iṣẹ́ Wikimedia Foundation |
Wikimedia project | Iṣẹ́-àkànṣe Wikimedia |
Wikimedia projects | Àwọn iṣẹ́-àkànṣe Wikimedia |
Wikimedia Summit | Wikimedia Summit |
Wikinews | Wikinews |
Wikipedia | Wikipedia |
Wikiquote | Wikiquote |
Wikisource | Wikisource |
Wikispecies | Wikispecies |
wikitext | wikitext |
wikitext editor | wikitext editor |
Wikiversity | Wikiversity |
Wikivoyage | Wikivoyage |
Wiktionary | Wiktionary |
working group | ẹgbẹ́ iṣẹ́ |